Saturday, 25 January 2014

  Bi Igba Ehin Ijapa Se Fo.
 Aalo o aalo, ni igba laelae, igba kan nlo igba kan nbo igba kan ko lo ile aye gbo. Alo mi dale ori Ijapa . Iyan mu ni ilu ijapa,  to bẹẹ gẹẹ awon ara ilu  se ipade bi awon ko se ni ku. Won pinnu lati sarajo ki gbogbo won lo wa onje ni ilu odikeji. Eni kan ni yio se asoju fun idile kookan, won o jeun , won o mu, awon asoju yio si ko onje wale fun gbogbo ebi won. Ilu odikeji yi jinna won ko le rin lo si ibe won nilati fo lo ni. Awon y da iykookan fun awon ti ko le fo, bi ijapa, okr , ehoro  ati bẹẹbẹẹ lo. Nigbati won de ibi ti won nlo ijapa ba awon iyoku re soro oni .o dara bia bay an oruko tuntun ti awon arailu yio ma pew a ni tori asa ilu yi ni yen. Onikaluku yan oruko titun. Okere ni ouun ni sare gunigi, ehoro ni oun ni sarewoiho. Ijapa ni oun o maa j gbogbo yin . Awon ara ilu oke fi tayotayo pade awon  alejo wonyi. Won dari won si aafin oba. Awon onis oba pon oti, won ro oka . Bi oni s ti ngbe ounj bo ijapa sare pade re ogba onj lowo r osi nnikan je. O so fun awon ore re ti won jo wa wipe ounje toun ni. Ope onise oba pada osi bere lowo r pe ounj tani eleyi? Onisoba da hun wipe ounj ti gbogbo yin ni. Won gbe mimu wa ijapa si tun se bẹẹ. Igba ti il su ijapa di eyi to sku ninu ounjosi so fun awo n lgb r pe ile ya.  Ebi pa okr, ori r le koko ,  ebi pa ehoro , eyin r pa keke, ebi pa  yga o rojo, ebi pa asa o ra baba , ebi pa  atiala o sokun, abi pa aparo o pose , ebi pa owiwi ,o moju. Won bo sona won nfo pada bo wa’le ijapa ba dahun oni awon ilu yi dara pupo, j ki a maa wa lẹẹkan l’os. Ka jun ka yo batakun. Inu awon y ko dun lati gbo roro ti ijapa so nitori won ko j oun kaknkan. Won binu onikaluku gba iyẹ ẹyokan r lara ija pa . Gbogbo wa la mo wipe Ijapa ko le fo, ijapa jabo sil lati oju orun, igba yin re si fo ka yanga. Awon eera lo pejo ti won sa igbare ti won sit un to. I gba ijapa ti di woko woko lati igba naa.

Itan yi ko wa pe ki a ma se hu iwa wobia si omonikeji wa.

No comments:

Post a Comment