Saturday, 25 January 2014

  Bi Igba Ehin Ijapa Se Fo.
 Aalo o aalo, ni igba laelae, igba kan nlo igba kan nbo igba kan ko lo ile aye gbo. Alo mi dale ori Ijapa . Iyan mu ni ilu ijapa,  to bẹẹ gẹẹ awon ara ilu  se ipade bi awon ko se ni ku. Won pinnu lati sarajo ki gbogbo won lo wa onje ni ilu odikeji. Eni kan ni yio se asoju fun idile kookan, won o jeun , won o mu, awon asoju yio si ko onje wale fun gbogbo ebi won. Ilu odikeji yi jinna won ko le rin lo si ibe won nilati fo lo ni. Awon y da iykookan fun awon ti ko le fo, bi ijapa, okr , ehoro  ati bẹẹbẹẹ lo. Nigbati won de ibi ti won nlo ijapa ba awon iyoku re soro oni .o dara bia bay an oruko tuntun ti awon arailu yio ma pew a ni tori asa ilu yi ni yen. Onikaluku yan oruko titun. Okere ni ouun ni sare gunigi, ehoro ni oun ni sarewoiho. Ijapa ni oun o maa j gbogbo yin . Awon ara ilu oke fi tayotayo pade awon  alejo wonyi. Won dari won si aafin oba. Awon onis oba pon oti, won ro oka . Bi oni s ti ngbe ounj bo ijapa sare pade re ogba onj lowo r osi nnikan je. O so fun awon ore re ti won jo wa wipe ounje toun ni. Ope onise oba pada osi bere lowo r pe ounj tani eleyi? Onisoba da hun wipe ounj ti gbogbo yin ni. Won gbe mimu wa ijapa si tun se bẹẹ. Igba ti il su ijapa di eyi to sku ninu ounjosi so fun awo n lgb r pe ile ya.  Ebi pa okr, ori r le koko ,  ebi pa ehoro , eyin r pa keke, ebi pa  yga o rojo, ebi pa asa o ra baba , ebi pa  atiala o sokun, abi pa aparo o pose , ebi pa owiwi ,o moju. Won bo sona won nfo pada bo wa’le ijapa ba dahun oni awon ilu yi dara pupo, j ki a maa wa lẹẹkan l’os. Ka jun ka yo batakun. Inu awon y ko dun lati gbo roro ti ijapa so nitori won ko j oun kaknkan. Won binu onikaluku gba iyẹ ẹyokan r lara ija pa . Gbogbo wa la mo wipe Ijapa ko le fo, ijapa jabo sil lati oju orun, igba yin re si fo ka yanga. Awon eera lo pejo ti won sa igbare ti won sit un to. I gba ijapa ti di woko woko lati igba naa.

Itan yi ko wa pe ki a ma se hu iwa wobia si omonikeji wa.
 Bi ijapa se y ikun gbndu
Aalo o aalo, ni igba laelae, igba kan nlo igba kan nbo igba kan ko lo ile aye gbo. Alo mi da leri ijapa ati Yannibo iyawo rẹ. Lhin opolopo odun ti ijapa ati Yannibo ko tii se abiyamo won lo si ile babalawo ti yio ba won da si. Babalawo y won wo osi ni ob eto ni oun o se fun Yannibo jẹ. Oni ki won sanwo eto ohun yio ja ewe ati egbo ati gbogbo ohun ti o ma j ki Yannibo loyun ki osi bimo. Oni bi oba to ojo mẹta ki ijapa wa, lati gbe ikoko obnaa lo si ile fun iyawo r.
Ijapa de ni ojo kta osi gbe ikoko ob na. Baba alawo kilo fun gidi gidi wipe Yannibo lo gbodo da j ob na, lyin eyi ijapa le la ikoko. Ijapa kanju gbe ikoko, o nlo si ile plu ikoko ob. Okan ijapa ko kuro ni ob yi. O si wo, o to eti la. Ode ikoko o tun bosi ona.  Bi o ti nrin lo nfi s ko to n duro to nto ob la. Laip Ijapa ri wipe oun ti j ikoko ob de ilaji lo ba kuku j gbogbo tan. Ogbe ikoko leri o bo si ona ile okan re ss bale. Kio to dele iku r bẹrẹ si fa wu. Igba ti Yannibo ri oko re, oni ta l beere o, ko s’oko mi nile o. Ijapa ni Yannibo emi ma ni. Yannibo ro pe oyi l’onse oun o bu s’rin oni bi o ba tan ara r tan, ko wa iro mi pa.    O j tete ma lo ile r oko mi fr de. Ijapa ko yin si yannibo oni wo mi lati yin , Yannibo ri wipe oko oun ni, ogba ikoko lori rẹ, O la ob kekere to sku. Nigbati ose di ara brẹ sii ni ijapa, iku r tubo nga si. Iku iyawo r naa nga. Ijapa ba pada lo si odo babalawo, ofi orin b’nu oni :
Babalawo mo wa bb...alugbirin,
babalawo mo wa bb.....alugbirin.
Ogun t’o se fun mi lẹẹkan.....alugbiirin,
 gbongbo lo ko mii ls....alugbinrin,
 mo  fo wo bab mo mu knu...alugbinrin,
 mo bo ju wo kun o ri gbndu....alugbinrin,
 babalawo mo wa bb.....alugbirin. .
Baba lawo ko si nile, oti lo re irin ajo. Odi ojo ti babalawo ba ti ajo de ki ikun Ijapa to le fa di.

Itan yi ko w ape k’ama se oju kokoro. Oju kokoro ko dara.

Sunday, 24 November 2013

Ijapa di Ana Oba.



Kiniun j
ba ni ilu awon ranko. Iyan mu gidigidi, ojo ko r fun dun mta gbako. Gbogbo igi igbo gb, eweko jona ml awn ranko kosi ri ounj j deede. Iyan yi le de bi pe Kiniun ba gan ko ri ounj jẹ deede. kan ba bajẹ, o si aar. O ranṣẹ pe adahune.


Adahune de, o ki kabiyesi o si wipe ba ni lati e etutu, ki ilu le toro ni oju aye r. Odidi erin ni ao fi rub, niwaju aafin laarin ilu. Eyi ni wipe wn yio mu erin wa si aafin, ni aaye lati fi e etutu.

ba mi kan l o ni iyn ko le eeṣe. Bawo ni ao ṣe mu erin w’lu. Tani yio mu erin w’lu. Lhin igba ti erin ba w ilu tan tani yio le pa erin. Adahune ni bi wn ba ti ri erin ki wn rane si oun lati e etutu.

   Ọkan ba rẹwẹsi, osi ke si iyaw r pe , bawo ni oun yio ṣe e etutu yi?     Iyawo r ni ko s fun awn ijoye ki wn o yan d aperin lati l mu erin wa.  d apeerin wipe erin ko le ee mu laaye.

 ba ni ki akede ke si gbogbo ara ilu wipe nikeni ti o ba le mu erin wilu laaye ti oun yio fi ṣe etutu, oun o fun ni mbinrin ohun lati fi ’aya plu dukia lplp.
Ijapa gb akede, o da gbere fun iyawo re Yannibo oni, “mo ti f iyawo le , m ba si ni”. Yannibo bu si rin oni, “boo ba tan ara r tan, ko wa ir mi pa”.

Ijapa gbera o di aafin, o ba plp jagunjagun ti wn ti de iwaju r. Olukaluku a wle s’iwaju ba, wn si s gbogbo bi awon oe d okun mu erin, ugbon o ku bi wn yio e faa w ilu laaye.  Ẹlomiran ni oun o fun eerin ni ogun orun, oun yio si gbe w ilu, ugbn ori ajanaku kii e ru mde, erin ko e e gbe.

Ni paripari o ṣẹku ijapa nikan.  Il ti u, Ijapa ti sun l osi nhan run. Awn ijoye ji i. O wle siwaju ba oni ‘Ao merin j’ba ...wtuwl’, ao m’erin jba wtuwl. Awn ms fa ida y wn fẹẹ pa ijapa . Ijapa sr oni orin ti o ma k l’j mta si isinyi niyn.  A o gb koto nla si iwaju aafin a o da ni bo, a o wa gbe aga ba lee. Gbogbo ara ilu yio ko si as y, wn o ma e ayy

Emi o l si ibudo erin ngo  si l s fun wipe ati le kiniun ba kuro l’ori it. Oun erin l’okan ti ao fi j ba wa. Gbogbo awn jgbn fori kori wn si wipe, kosi oun to dara to gbn ti ijapa mu wa.  Kabiyesi faram ete ijapa.


  Ni j kta, ijapa  ati onilu  gbera wn l si ibudo erin. Bi ijapa ṣe ri erin lkankan o bu si orin oni: ‘A o m’erin jba’,  awon onilu ba ngbee pe ‘wtuwl’.
Ao m’erin j’ba..... wtuwlẹ                           
ba alade,...............wtuwl
Ao m’erin j’ba...... wtuwl

Erin ta eti kan, oni emi naa , Ijapa dahun pe bẹẹni, gbogbo awon onilu si nki erin Kabiyesi. Erin mura o tle ijapa. Igbati wn w inu ilu ijapa tun fi orin bnu:
 ‘A o m’erin jba’, awon ara ilu ba ngbe pe ‘wtuwl’.
Ao m’erin j’ba........ wtuwl
ba alade,................ wtuwl
Ao m’erin j’ba........ wtuwl
Gbogbo won fi t’ijo t’ay tle ijapa ati erin l si ori it kabiyesi r. Bi erin e joko si ori aga gbogbo ni jin si isal, erin ja si koto, adahunse fi erin e etutu. Ojo br si r, eweko ntutu minijj, gbogbo ranko njun, ilu si toro. Ara kiniun ba ya gaga, O fi mbinrin r fun ijapa ko fi e aya. O fun ni dukia rptẹ. Ijapa si di ana ba.