Sunday, 24 November 2013

Ijapa di Ana Oba.



Kiniun j
ba ni ilu awon ranko. Iyan mu gidigidi, ojo ko r fun dun mta gbako. Gbogbo igi igbo gb, eweko jona ml awn ranko kosi ri ounj j deede. Iyan yi le de bi pe Kiniun ba gan ko ri ounj jẹ deede. kan ba bajẹ, o si aar. O ranṣẹ pe adahune.


Adahune de, o ki kabiyesi o si wipe ba ni lati e etutu, ki ilu le toro ni oju aye r. Odidi erin ni ao fi rub, niwaju aafin laarin ilu. Eyi ni wipe wn yio mu erin wa si aafin, ni aaye lati fi e etutu.

ba mi kan l o ni iyn ko le eeṣe. Bawo ni ao ṣe mu erin w’lu. Tani yio mu erin w’lu. Lhin igba ti erin ba w ilu tan tani yio le pa erin. Adahune ni bi wn ba ti ri erin ki wn rane si oun lati e etutu.

   Ọkan ba rẹwẹsi, osi ke si iyaw r pe , bawo ni oun yio ṣe e etutu yi?     Iyawo r ni ko s fun awn ijoye ki wn o yan d aperin lati l mu erin wa.  d apeerin wipe erin ko le ee mu laaye.

 ba ni ki akede ke si gbogbo ara ilu wipe nikeni ti o ba le mu erin wilu laaye ti oun yio fi ṣe etutu, oun o fun ni mbinrin ohun lati fi ’aya plu dukia lplp.
Ijapa gb akede, o da gbere fun iyawo re Yannibo oni, “mo ti f iyawo le , m ba si ni”. Yannibo bu si rin oni, “boo ba tan ara r tan, ko wa ir mi pa”.

Ijapa gbera o di aafin, o ba plp jagunjagun ti wn ti de iwaju r. Olukaluku a wle s’iwaju ba, wn si s gbogbo bi awon oe d okun mu erin, ugbon o ku bi wn yio e faa w ilu laaye.  Ẹlomiran ni oun o fun eerin ni ogun orun, oun yio si gbe w ilu, ugbn ori ajanaku kii e ru mde, erin ko e e gbe.

Ni paripari o ṣẹku ijapa nikan.  Il ti u, Ijapa ti sun l osi nhan run. Awn ijoye ji i. O wle siwaju ba oni ‘Ao merin j’ba ...wtuwl’, ao m’erin jba wtuwl. Awn ms fa ida y wn fẹẹ pa ijapa . Ijapa sr oni orin ti o ma k l’j mta si isinyi niyn.  A o gb koto nla si iwaju aafin a o da ni bo, a o wa gbe aga ba lee. Gbogbo ara ilu yio ko si as y, wn o ma e ayy

Emi o l si ibudo erin ngo  si l s fun wipe ati le kiniun ba kuro l’ori it. Oun erin l’okan ti ao fi j ba wa. Gbogbo awn jgbn fori kori wn si wipe, kosi oun to dara to gbn ti ijapa mu wa.  Kabiyesi faram ete ijapa.


  Ni j kta, ijapa  ati onilu  gbera wn l si ibudo erin. Bi ijapa ṣe ri erin lkankan o bu si orin oni: ‘A o m’erin jba’,  awon onilu ba ngbee pe ‘wtuwl’.
Ao m’erin j’ba..... wtuwlẹ                           
ba alade,...............wtuwl
Ao m’erin j’ba...... wtuwl

Erin ta eti kan, oni emi naa , Ijapa dahun pe bẹẹni, gbogbo awon onilu si nki erin Kabiyesi. Erin mura o tle ijapa. Igbati wn w inu ilu ijapa tun fi orin bnu:
 ‘A o m’erin jba’, awon ara ilu ba ngbe pe ‘wtuwl’.
Ao m’erin j’ba........ wtuwl
ba alade,................ wtuwl
Ao m’erin j’ba........ wtuwl
Gbogbo won fi t’ijo t’ay tle ijapa ati erin l si ori it kabiyesi r. Bi erin e joko si ori aga gbogbo ni jin si isal, erin ja si koto, adahunse fi erin e etutu. Ojo br si r, eweko ntutu minijj, gbogbo ranko njun, ilu si toro. Ara kiniun ba ya gaga, O fi mbinrin r fun ijapa ko fi e aya. O fun ni dukia rptẹ. Ijapa si di ana ba.